Itan
Ka gbogbo eÀrọ̀nì ò wálé oníkòyí ò simi ogun lílọ
Ẹ kú dédé àsìkò yìí gbogbo olólùfẹ́ ojú ìwé yìí, látàrí ìbéèrè tí mo béèrè tí kò si sii ẹni tí ó gbà á. Ìbéèrè náà ni wípé ìtàn wo …
Ewi
Ka gbogbo eÌWÀ
ÌWÀ Tọju ìwà rẹ ọ̀rẹ́ mí, Ọlá a máa tàn nílé ẹni, Ẹwà ási máa lọ lára ènìyàn, Ṣùgbọ́n ìwà ní o ku ní kú nígbà abádé inú saare, Èéfín …
Eko
Ka gbogbo eÀṣà Ìgbéyàwó
Àṣà Ìgbéyàwó Ìgbéyàwó jẹ ìsodọ̀kan ọkùnrin àti obìnrin tí ó ti bàlágà,láti jo máa gbé papọ̀ gẹ́gẹ́ bí ọkọ àti aya. Tí aba fẹ́ kí ìgbéyàwó wáyé ní ilè Yorùbá …
Alo
Ka gbogbo eÌJÀPÁ ÀTI ÒGBÓJÚ ÒDE
Àlọ́ oooo Àlọ̀ ọọọọ Ọkunrin kan wa láyé àtijọ́, Ògbójú-ọdẹ ni, ṣùgbọ́n bi ó ti pa ẹran tó, kò fi dá nkan ṣe. Ọ̀pọ̀ igbà, ki ri ẹran ti ó …