Skip to content
January 28, 2021
  • Facebook
  • Twitter
  • Instagram
  • YouTube
Èdè Yorùbá Rẹwà

Èdè Yorùbá Rẹwà

A dá sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò nípa èdè Yorùbá, àṣà àti ìṣe ilẹ̀ kóòtù ojire. Kíkó àwọn ọmọ wa ni Èdè Yorùbá

  • Ìtàn
  • Ewì
  • Oríkì
  • Àlọ́
  • È̩kọ́
  • Fọ́nrán
  • Nípa Wa
  • Ẹ kàn sí wa
Main Menu

Àlọ́

Àlọ́

ÌJÀPÁ ÀTI ÒGBÓJÚ ÒDE

January 28, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

Àlọ́ oooo Àlọ̀ ọọọọ Ọkunrin kan wa láyé àtijọ́, Ògbójú-ọdẹ ni, ṣùgbọ́n bi ó ti pa ẹran tó, kò fi dá nkan ṣe.  Ọ̀pọ̀ igbà, ki ri ẹran ti ó …

Kaa Siwaju
Àlọ́

Ìgbín àti Ìjàpá

January 28, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

Àlọ́ oooo Àlọ̀ ọọọọ Àlọ́ yìí dá lórí ìgbín àti Ìjàpá Ní ayé àtijó, ìgbín àti Ìjàpá jọ ń ṣe ọ̀rẹ́. Ọ̀rẹ́ kòríkòsùn ni wọ́n ṣe. Gbogbo ìlú ló sì …

Kaa Siwaju
Àlọ́

Àlọ́ Àpagbè – Ìjàpá Ati Ẹyẹ Àdàbà

January 24, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

Èyí ni Àlọ́ àpagbè fún gbogbo olólùfẹ́ ojú ìwé yìí, mọ lérò wípé ẹ ò gbádùn ẹ. Àlọ́ oooo Àlọ́ ọọọọ Àlọ́ yìí dá lórí Ìjàpá ati ẹyẹ Àdàbà Gégé …

Kaa Siwaju

Oro Tuntun

  • Àrọ̀nì ò wálé oníkòyí ò simi ogun lílọ
  • ÒÒRÙN Ati ÒṢÙPÁ
  • KÍ LO RÍ L’Ọ́BẸ̀ TÍ Ó FI WAARO ỌWỌ́
  • ORÍKÌ
  • Àṣà Ìgbéyàwó

Eka Oro

  • Ìtàn
  • Ewì
  • Oríkì
  • Àlọ́
  • È̩kọ́
  • Fọ́nrán
  • Nípa Wa
  • Ẹ kàn sí wa

E Tele Wa Lori Facebook

Facebook Pagelike Widget

Twitter

Èdè Yorùbá RewàFollow

Èdè Yorùbá Rewà
edeyorubarewaÈdè Yorùbá Rewà@edeyorubarewa·
17h

Kíni orúkọ ti ẹ̀yin ń pe ohun tó wà nínú àwòrán yìí?👇👇👇 @ Birmingham, United Kingdom https://www.instagram.com/p/CKjqxdApoSn/?igshid=1w72cg2jp5cv7

Reply on Twitter 1354487086829740038Retweet on Twitter 1354487086829740038Like on Twitter 1354487086829740038Twitter 1354487086829740038
edeyorubarewaÈdè Yorùbá Rewà@edeyorubarewa·
24 Jan

Just posted a video https://www.instagram.com/p/CKbSOAbJ2zN/?igshid=1ltqhkcqri8je

Reply on Twitter 1353306213837103104Retweet on Twitter 1353306213837103104Like on Twitter 1353306213837103104Twitter 1353306213837103104
edeyorubarewaÈdè Yorùbá Rewà@edeyorubarewa·
14 Jan

Àádọ́ta ọdún lórí ite.
Ikú bàbá yèyé,
ọmọ Ikú tí Ikú ò gbọdò pa,
Ọmọ àrùn tá'rùn ò gbọdò se.

Aláàfin Ọ̀yọ́ Oba Lamidi Adeyemi III
#AlaafinOyo
#ObaOyo
#ObaIleYoruba
#EdeYorubaRewa @ Birmingham, United Kingdom https://www.instagram.com/p/CKBJqeBpDMk/?igshid=1touf53vuza7e

Reply on Twitter 1349628103245651968Retweet on Twitter 1349628103245651968Like on Twitter 1349628103245651968Twitter 1349628103245651968
Load More...

Èdè Yorùbá Rẹwà

A dá ojú ẹ̀ro àyélujára yí sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò nípa èdè Yorùbá, àṣà àti ìṣe ilẹ̀ kóòtù ojire. Kíkó àwọn ọmọ wa ni Èdè Yorùbá. Semiat Olufunke Tiamiyu ni o n ko awon oro wonyii.

Etele Wa Lori

  • Facebook
  • Twitter
  • Instagram
  • YouTube

Eka Oro

  • Ìtàn
  • Ewì
  • Oríkì
  • Àlọ́
  • È̩kọ́
  • Fọ́nrán
  • Nípa Wa
  • Ẹ kàn sí wa

E Tele Wa Lori Facebook

Facebook Pagelike Widget
Copyright © 2021 Èdè Yorùbá Rẹwà.
Powered by WordPress and HitMag.
error

Nje e gbadun ohun ti eka, e tele wa lori:

  • Facebook
    Facebook
    fb-share-icon
  • Twitter
    Follow Me
  • YouTube
    YouTube
  • Instagram