Skip to content
January 28, 2021
  • Facebook
  • Twitter
  • Instagram
  • YouTube
Èdè Yorùbá Rẹwà

Èdè Yorùbá Rẹwà

A dá sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò nípa èdè Yorùbá, àṣà àti ìṣe ilẹ̀ kóòtù ojire. Kíkó àwọn ọmọ wa ni Èdè Yorùbá

  • Ìtàn
  • Ewì
  • Oríkì
  • Àlọ́
  • È̩kọ́
  • Fọ́nrán
  • Nípa Wa
  • Ẹ kàn sí wa
Main Menu

È̩kọ́

È̩kọ́

Àṣà Ìgbéyàwó

January 29, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

Àṣà Ìgbéyàwó Ìgbéyàwó jẹ ìsodọ̀kan ọkùnrin àti  obìnrin tí ó ti bàlágà,láti jo máa gbé papọ̀ gẹ́gẹ́ bí ọkọ àti aya. Tí aba fẹ́ kí ìgbéyàwó wáyé ní ilè Yorùbá …

Kaa Siwaju
È̩kọ́

ÒTÚÁ MÉJÌ – Apá Kejì

January 28, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

Apá kejì OTUA MÉJÌ Ó di wí pé Bí ẹnìkán bá ń sọ ọmọ lórúkọ Àwọn ọmọ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta yìí ó lọ síbẹ̀. Bí òkú kú fún ẹnìkan, Wọn á ránńṣẹ́ …

Kaa Siwaju
È̩kọ́

ÒTÚÁ MÉJÌ – Apá Kínní

January 28, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

Ẹsẹ IFÁ Apá Kínní    ÒTÚÁ MÉJÌ Wútùwútù yáákí; Wútùwútù yám̀bèlé, Ká súré pátápirá, Ká fẹ̀wù àlàárì fọnkun àmọ́di, Lékèélékèé, ẹyẹ ìmọ̀le, Bó bá ṣí lórí ọ̀pọ̀tọ̀, A bà sórí òrom̀bó, …

Kaa Siwaju
È̩kọ́

A B D Olówe

January 28, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

A______ Àgbà kìí wà lọ́jà, k’órí ọmọ tuntun ó wó. B______ Bá mi na ọmọ mi, kò dénu ọlọ́mọ. D______ Dídà ló  dà l’ọmọ dé ẹ̀gbẹ́, ẹ̀gbẹ́ kìí ṣe ilé …

Kaa Siwaju

Oro Tuntun

  • Àrọ̀nì ò wálé oníkòyí ò simi ogun lílọ
  • ÒÒRÙN Ati ÒṢÙPÁ
  • KÍ LO RÍ L’Ọ́BẸ̀ TÍ Ó FI WAARO ỌWỌ́
  • ORÍKÌ
  • Àṣà Ìgbéyàwó

Eka Oro

  • Ìtàn
  • Ewì
  • Oríkì
  • Àlọ́
  • È̩kọ́
  • Fọ́nrán
  • Nípa Wa
  • Ẹ kàn sí wa

E Tele Wa Lori Facebook

Facebook Pagelike Widget

Twitter

Èdè Yorùbá RewàFollow

Èdè Yorùbá Rewà
edeyorubarewaÈdè Yorùbá Rewà@edeyorubarewa·
54m

Kíni orúkọ ti ẹ̀yin ń pe ohun tó wà nínú àwòrán yìí?👇👇👇

Orúkọ márùn-ún ni mo mọn sí. @ Somewhere in the Universe https://www.instagram.com/p/CKljWJpJ-Rr/?igshid=nor3ftt6dczu

Reply on Twitter 1354751128244727810Retweet on Twitter 1354751128244727810Like on Twitter 1354751128244727810Twitter 1354751128244727810
edeyorubarewaÈdè Yorùbá Rewà@edeyorubarewa·
18h

Kíni orúkọ ti ẹ̀yin ń pe ohun tó wà nínú àwòrán yìí?👇👇👇 @ Birmingham, United Kingdom https://www.instagram.com/p/CKjqxdApoSn/?igshid=1w72cg2jp5cv7

Reply on Twitter 1354487086829740038Retweet on Twitter 1354487086829740038Like on Twitter 1354487086829740038Twitter 1354487086829740038
edeyorubarewaÈdè Yorùbá Rewà@edeyorubarewa·
24 Jan

Just posted a video https://www.instagram.com/p/CKbSOAbJ2zN/?igshid=1ltqhkcqri8je

Reply on Twitter 1353306213837103104Retweet on Twitter 1353306213837103104Like on Twitter 1353306213837103104Twitter 1353306213837103104
Load More...

Èdè Yorùbá Rẹwà

A dá ojú ẹ̀ro àyélujára yí sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò nípa èdè Yorùbá, àṣà àti ìṣe ilẹ̀ kóòtù ojire. Kíkó àwọn ọmọ wa ni Èdè Yorùbá. Semiat Olufunke Tiamiyu ni o n ko awon oro wonyii.

Etele Wa Lori

  • Facebook
  • Twitter
  • Instagram
  • YouTube

Eka Oro

  • Ìtàn
  • Ewì
  • Oríkì
  • Àlọ́
  • È̩kọ́
  • Fọ́nrán
  • Nípa Wa
  • Ẹ kàn sí wa

E Tele Wa Lori Facebook

Facebook Pagelike Widget
Copyright © 2021 Èdè Yorùbá Rẹwà.
Powered by WordPress and HitMag.
error

Nje e gbadun ohun ti eka, e tele wa lori:

  • Facebook
    Facebook
    fb-share-icon
  • Twitter
    Follow Me
  • YouTube
    YouTube
  • Instagram