Skip to content
February 4, 2023
  • Facebook
  • Twitter
  • Instagram
  • YouTube
Èdè Yorùbá Rẹwà

Èdè Yorùbá Rẹwà

A dá sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò nípa èdè Yorùbá, àṣà àti ìṣe ilẹ̀ kóòtù ojire. Kíkó àwọn ọmọ wa ni Èdè Yorùbá

  • Ìtàn
  • Ewì
  • Oríkì
  • Àlọ́
  • È̩kọ́
  • Fọ́nrán
  • Nípa Wa
  • Ẹ kàn sí wa
Main Menu

Ìtàn

Ìtàn

Àrọ̀nì ò wálé oníkòyí ò simi ogun lílọ

January 29, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - 1 Comment

Ẹ kú dédé àsìkò yìí gbogbo olólùfẹ́ ojú ìwé yìí, látàrí ìbéèrè tí mo béèrè tí kò si sii ẹni tí ó gbà á. Ìbéèrè náà ni wípé ìtàn wo …

Àrọ̀nì ò wálé oníkòyí ò simi ogun lílọ Kaa Siwaju
Ìtàn

ÒÒRÙN Ati ÒṢÙPÁ

January 29, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

ÒÒRÙN Ati ÒṢÙPÁ nígbà ìwásẹ̀, ọba ọdẹ Ọ̀run níse alákoso ohun gbogbo, ìkáwọ́ rẹ̀ ṣì ni gbogbo ohun tí a dá wà.ọba ọdẹ Ọ̀run ní ìyàwó , ósì tún bí …

ÒÒRÙN Ati ÒṢÙPÁ Kaa Siwaju
Ìtàn

KÍ LO RÍ L’Ọ́BẸ̀ TÍ Ó FI WAARO ỌWỌ́

January 29, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - 2 Comments.

Ìtàn tí ó rò mó òwe Yorùbá yìí,                   “Kí lo rí l’ọ́bẹ̀ tí fi waaro ọwọ́.” Ní bí ọdún díè sẹ́yìn, ìlú kan wà tí wọ́n ń pè ní Kuo, …

KÍ LO RÍ L’Ọ́BẸ̀ TÍ Ó FI WAARO ỌWỌ́ Kaa Siwaju
Ìtàn

ẸNU

January 28, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

ẸNU Ọmọ aráyé ẹ jẹ́ ká ṣọ́ra fẹ́nu Ẹnu ní í lani Ẹnu ní í pani Ẹnu ní jin ni sọ́fìn Ẹnu làá fi ń tún ènìyàn ṣe Ẹnu la …

ẸNU Kaa Siwaju
Ìtàn

Ṣe Boo Tí Mọ Ẹlẹ́wà Sàpọ́n

January 24, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

Ẹ kú dédé àsìkò yìí, ṣe àlàáfíà ni ẹ wà? Fún ìgbádùn àwọn tí ṣẹ̀ṣẹ̀ darapọ̀ mọ ojú ìwé yìí. Ìtàn aladidun fún ìgbádùn yìí,ìtàn tí ó rò mó ọ̀rọ̀ …

Ṣe Boo Tí Mọ Ẹlẹ́wà Sàpọ́n Kaa Siwaju
Ìtàn

Ìtàn Irú

January 24, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

Òkèmẹ̀sí jẹ́ ilu kan ní ìlú Èkìtì, àwọn ìdí ilé kan wa ní Òkèmẹ̀sí tí òwe yìí tí wá tí wọn kìí jẹ IRÚ. Wọn a má ń sọ wípé …

Ìtàn Irú Kaa Siwaju
Ìtàn

Ìtàn Bàbá Alàjọ Sómólú

January 24, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

Alphaeus Taiwo Olunaike jẹ́ orúkọ  tí gbogbo ọmọ orílè èdè Nàìjíríà o mọ, ṣùgbọ́n tí wọn ba gbo Baba Alàjọ Somolu, Gbogbo la mọ orúkọ náà. Bàbá Alàjọ Sómólú jẹ́ …

Ìtàn Bàbá Alàjọ Sómólú Kaa Siwaju

Oro Tuntun

  • Àrọ̀nì ò wálé oníkòyí ò simi ogun lílọ
  • ÒÒRÙN Ati ÒṢÙPÁ
  • KÍ LO RÍ L’Ọ́BẸ̀ TÍ Ó FI WAARO ỌWỌ́
  • ORÍKÌ
  • Àṣà Ìgbéyàwó

Eka Oro

  • Ìtàn
  • Ewì
  • Oríkì
  • Àlọ́
  • È̩kọ́
  • Fọ́nrán
  • Nípa Wa
  • Ẹ kàn sí wa

E Tele Wa Lori Facebook

Facebook Pagelike Widget

Twitter

Èdè Yorùbá RewàFollow

Èdè Yorùbá tí ó rẹwà jẹ́ ohun tí mo dá sílè láti gbé èdè Yorùbá lárugẹ,láti jẹ́ kí àwọn ènìyàn mọ wípé èdè Yorùbá dùn púpò

Èdè Yorùbá Rewà
edeyorubarewaÈdè Yorùbá Rewà@edeyorubarewa·
6 Oct

Beautiful Yorùbá 🥰: there are 60+ million Yorùbá speakers in the world today. Through music 🎶 , film 📼, sports 🏃🏾‍♂️ and travel ✈️, Yorùbá Language is going places. If you have a beautiful Yorùbá name(s)

Reply on Twitter 1578070710769025030Retweet on Twitter 1578070710769025030Like on Twitter 15780707107690250303Twitter 1578070710769025030
Retweet on TwitterÈdè Yorùbá Rewà Retweeted
simplepcSimon 🔴 Salvin@simplepc·
27 May

@BBC @BBCnews shamed for using a free @Zoom account 😂
Do you need to start a GoFundMe page?

Reply on Twitter 1530133755259670530Retweet on Twitter 15301337552596705304Like on Twitter 15301337552596705305Twitter 1530133755259670530
edeyorubarewaÈdè Yorùbá Rewà@edeyorubarewa·
1 Jan 2022

Ọdún yìí á yabo fún gbogbo wa.
Àmín àṣẹ Èdùmàrè
#EdeYorubaRewa
#YorubaDunLede
#Oduntuntun
#2022 @ Greenford/ Greater London https://www.instagram.com/p/CYLcVAwI093/?utm_medium=twitter

Reply on Twitter 1477177320775602178Retweet on Twitter 1477177320775602178Like on Twitter 14771773207756021781Twitter 1477177320775602178
Load More...

Èdè Yorùbá Rẹwà

A dá ojú ẹ̀ro àyélujára yí sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò nípa èdè Yorùbá, àṣà àti ìṣe ilẹ̀ kóòtù ojire. Kíkó àwọn ọmọ wa ni Èdè Yorùbá. Semiat Olufunke Tiamiyu ni o n ko awon oro wonyii.

Etele Wa Lori

  • Facebook
  • Twitter
  • Instagram
  • YouTube

Eka Oro

  • Ìtàn
  • Ewì
  • Oríkì
  • Àlọ́
  • È̩kọ́
  • Fọ́nrán
  • Nípa Wa
  • Ẹ kàn sí wa

E Tele Wa Lori Facebook

Facebook Pagelike Widget
Copyright © 2023 Èdè Yorùbá Rẹwà.
Powered by WordPress and HitMag.
error

Nje e gbadun ohun ti eka, e tele wa lori:

  • Facebook
    Facebook
    fb-share-icon
  • Twitter
    Follow Me
  • YouTube
    YouTube
  • Instagram