Nípa Èdè Yorùbá Rẹwà

A dá ojú ẹ̀ro àyélujára yí sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò nípa èdè Yorùbá, àṣà àti ìṣe ilẹ̀ kóòtù ojire. Kíkó àwọn ọmọ wa ni Èdè Yorùbá. Semiat Olufunke Tiamiyu ni o n ko awon oro wonyii.

A n lo oju ẹ̀ro àyélujára yii lati polongo ati fonrere imo nipa ede Yoruba gege bi a ti mo wipe laye ode oni, ede Yoruba ti di oun ti a ti n fi owo roo seyin ni eyi ti ko si bojumu rara.

Orisirisi itan, ewi, alo, ati awon eko ni a o ma ko arawa lori ero ayelujara yii. E o ni kuna tabi se iye meji pe e darapo mowa. 

 E seun!!!