Àrọ̀nì ò wálé oníkòyí ò simi ogun lílọ
Ẹ kú dédé àsìkò yìí gbogbo olólùfẹ́ ojú ìwé yìí, látàrí ìbéèrè tí mo béèrè tí kò si sii ẹni tí ó gbà á. Ìbéèrè náà ni wípé ìtàn wo …
Àrọ̀nì ò wálé oníkòyí ò simi ogun lílọ Kaa SiwajuA dá sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò nípa èdè Yorùbá, àṣà àti ìṣe ilẹ̀ kóòtù ojire. Kíkó àwọn ọmọ wa ni Èdè Yorùbá
Ẹ kú dédé àsìkò yìí gbogbo olólùfẹ́ ojú ìwé yìí, látàrí ìbéèrè tí mo béèrè tí kò si sii ẹni tí ó gbà á. Ìbéèrè náà ni wípé ìtàn wo …
Àrọ̀nì ò wálé oníkòyí ò simi ogun lílọ Kaa SiwajuÒÒRÙN Ati ÒṢÙPÁ nígbà ìwásẹ̀, ọba ọdẹ Ọ̀run níse alákoso ohun gbogbo, ìkáwọ́ rẹ̀ ṣì ni gbogbo ohun tí a dá wà.ọba ọdẹ Ọ̀run ní ìyàwó , ósì tún bí …
ÒÒRÙN Ati ÒṢÙPÁ Kaa SiwajuÌtàn tí ó rò mó òwe Yorùbá yìí, “Kí lo rí l’ọ́bẹ̀ tí fi waaro ọwọ́.” Ní bí ọdún díè sẹ́yìn, ìlú kan wà tí wọ́n ń pè ní Kuo, …
KÍ LO RÍ L’Ọ́BẸ̀ TÍ Ó FI WAARO ỌWỌ́ Kaa SiwajuORÍKÌ Àsà kan pàtàkì tí àwa Omo Yorùbá ń gbé sonù báyìí ni àsà oríkì kíkì. Ní ilè Yorùbá kò sí nnkan náà tí kò ní oríkì yálà eranko , …
ORÍKÌ Kaa SiwajuÀṣà Ìgbéyàwó Ìgbéyàwó jẹ ìsodọ̀kan ọkùnrin àti obìnrin tí ó ti bàlágà,láti jo máa gbé papọ̀ gẹ́gẹ́ bí ọkọ àti aya. Tí aba fẹ́ kí ìgbéyàwó wáyé ní ilè Yorùbá …
Àṣà Ìgbéyàwó Kaa SiwajuÌWÀ Tọju ìwà rẹ ọ̀rẹ́ mí, Ọlá a máa tàn nílé ẹni, Ẹwà ási máa lọ lára ènìyàn, Ṣùgbọ́n ìwà ní o ku ní kú nígbà abádé inú saare, Èéfín …
ÌWÀ Kaa SiwajuOÚNJẸ Mo gbà oúnjẹ gbó, oúnjẹ ni alákòóso ara, Oúnjẹ ní ọ̀rẹ́ àwò Iyán l’oúnjẹ, Ọkà Lógún, Àìní rárá lá ń jèko Ké ẹnu má di lè ní ti gúgúrú …
OÚNJẸ Kaa SiwajuAláyéLúwà Ìwòfà pàdé ọba lọ́nà, Ó gbàdúrà kẹ́lẹ́ kẹ́lẹ́, Pé bóyá orí a ṣé, Òun náà a dépò ọba, Láì mọ̀ wípé, Orí adé ò jẹ́rù ọba o fúyé, Lotito …
AláyéLúwà Kaa SiwajuÀÌRÍ’ṢẸ́ ṢE Ẹni tó jí láàárọ̀, To jáde nílé, Tó rí bìkan gbà lọ, Yálà iṣẹ́ ojúmọ́ tàbí toṣù, Tó dìrọ̀lẹ́ tó padà wálé, Tó rọ́wọ́ ti bàpò, Tàbí to …
ÀÌRÍ’ṢẸ́ ṢE Kaa SiwajuỌMỌDÉ Ewúré o mọlé olódì, Bẹ́ẹ̀ lọ̀rọ̀ ọmọdé rí, Bí a bá na ewúré, A gbo etí nù pépé, Ó tún padà síbi tí ó ti jìyà, Ọmọdé ò mọlé …
ỌMỌDÉ Kaa Siwaju