Àrọ̀nì ò wálé oníkòyí ò simi ogun lílọ
Ẹ kú dédé àsìkò yìí gbogbo olólùfẹ́ ojú ìwé yìí, látàrí ìbéèrè tí mo béèrè tí kò si sii ẹni tí ó gbà á. Ìbéèrè náà ni wípé ìtàn wo …
Àrọ̀nì ò wálé oníkòyí ò simi ogun lílọ Kaa SiwajuA dá sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò nípa èdè Yorùbá, àṣà àti ìṣe ilẹ̀ kóòtù ojire. Kíkó àwọn ọmọ wa ni Èdè Yorùbá
Ẹ kú dédé àsìkò yìí gbogbo olólùfẹ́ ojú ìwé yìí, látàrí ìbéèrè tí mo béèrè tí kò si sii ẹni tí ó gbà á. Ìbéèrè náà ni wípé ìtàn wo …
Àrọ̀nì ò wálé oníkòyí ò simi ogun lílọ Kaa SiwajuÒÒRÙN Ati ÒṢÙPÁ nígbà ìwásẹ̀, ọba ọdẹ Ọ̀run níse alákoso ohun gbogbo, ìkáwọ́ rẹ̀ ṣì ni gbogbo ohun tí a dá wà.ọba ọdẹ Ọ̀run ní ìyàwó , ósì tún bí …
ÒÒRÙN Ati ÒṢÙPÁ Kaa SiwajuÌtàn tí ó rò mó òwe Yorùbá yìí, “Kí lo rí l’ọ́bẹ̀ tí fi waaro ọwọ́.” Ní bí ọdún díè sẹ́yìn, ìlú kan wà tí wọ́n ń pè ní Kuo, …
KÍ LO RÍ L’Ọ́BẸ̀ TÍ Ó FI WAARO ỌWỌ́ Kaa SiwajuẸNU Ọmọ aráyé ẹ jẹ́ ká ṣọ́ra fẹ́nu Ẹnu ní í lani Ẹnu ní í pani Ẹnu ní jin ni sọ́fìn Ẹnu làá fi ń tún ènìyàn ṣe Ẹnu la …
ẸNU Kaa SiwajuẸ kú dédé àsìkò yìí, ṣe àlàáfíà ni ẹ wà? Fún ìgbádùn àwọn tí ṣẹ̀ṣẹ̀ darapọ̀ mọ ojú ìwé yìí. Ìtàn aladidun fún ìgbádùn yìí,ìtàn tí ó rò mó ọ̀rọ̀ …
Ṣe Boo Tí Mọ Ẹlẹ́wà Sàpọ́n Kaa SiwajuÒkèmẹ̀sí jẹ́ ilu kan ní ìlú Èkìtì, àwọn ìdí ilé kan wa ní Òkèmẹ̀sí tí òwe yìí tí wá tí wọn kìí jẹ IRÚ. Wọn a má ń sọ wípé …
Ìtàn Irú Kaa SiwajuAlphaeus Taiwo Olunaike jẹ́ orúkọ tí gbogbo ọmọ orílè èdè Nàìjíríà o mọ, ṣùgbọ́n tí wọn ba gbo Baba Alàjọ Somolu, Gbogbo la mọ orúkọ náà. Bàbá Alàjọ Sómólú jẹ́ …
Ìtàn Bàbá Alàjọ Sómólú Kaa Siwaju