ÒFIN FÒ LÓJÚ
Òfin fẹ́ oto níyàwó
Wọn bí ẹri lérè
Ẹri oni ìhòòhò
Ẹri tí ń yọ̀ ní nínú ìgbèkùn
Ẹri náà ní tun pani
Ọrẹ òfin ní ìfẹ́ jẹ
Ifẹ̀ alarifin òfin
Bí òru ati ọsan ní òfin àti ìfẹ́ rí
Ifẹ̀ ní akoja òfin
Ẹ ní ti o ba rú òfin yio jo lanba ni wà ju òfin
#Ìbéèrè Tí Mo fé bẹ̀rẹ̀ ni wí pé
#Ǹjẹ́ òfin de gbogbo ọmọ orílè èdè Nàìjíríà bí?