ÒFIN FÒ LÓJÚ
ÒFIN FÒ LÓJÚ Òfin fẹ́ oto níyàwó Wọn bí ẹri lérè Ẹri oni ìhòòhò Ẹri tí ń yọ̀ ní nínú ìgbèkùn Ẹri náà ní tun pani Ọrẹ òfin ní ìfẹ́ …
ÒFIN FÒ LÓJÚ Kaa SiwajuA dá sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò nípa èdè Yorùbá, àṣà àti ìṣe ilẹ̀ kóòtù ojire. Kíkó àwọn ọmọ wa ni Èdè Yorùbá
ÒFIN FÒ LÓJÚ Òfin fẹ́ oto níyàwó Wọn bí ẹri lérè Ẹri oni ìhòòhò Ẹri tí ń yọ̀ ní nínú ìgbèkùn Ẹri náà ní tun pani Ọrẹ òfin ní ìfẹ́ …
ÒFIN FÒ LÓJÚ Kaa SiwajuÌTẸ́LỌ́RÙN Ìtẹ́lọ́rùn ni baba ìwà, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe pàtàkì fọ́mọ adamọ, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe kókó, A gbọdọ̀ ni ìtẹ́lọ́rùn, Kí a le rí ayé gbé, Kí a le gbáyé ìrọ̀rùn, Aìní ni …
ÌTẸ́LỌ́RÙN Kaa SiwajuAṢỌ WÍWỌ Èèyàn lèyí ni àbí wèrè? Asínwín lèyí ni àbí abugije? Ṣé aṣọ lèyí abi kini? Ha! Ayé tí bàjé, Gbogbo ọmọ adáríhunrun tí sọ àṣà nù, A gbé …
AṢỌ WÍWỌ Kaa SiwajuIRE Ẹjẹ́ ké gb’ayé ṣe rere, Ọjọ́ a kú làá dère, Ènìyàn ò sunwòn láàyè, Ǹjẹ́ a lè rí ohun gidi sọ nípa rẹ tó bá kú, Àbí àwọn ènìyàn …
IRE Kaa SiwajuAHUN Iṣu mi ọdún yìí N kò ní fẹ́nìkan jẹ Àgbàdo tí mo gbìn yìí Kò ní kan ẹnìkan l’ẹ́nu Ẹran ọ̀yà tí mo yìnbọn sí Tíi mo ba ri …
AHUN Kaa SiwajuÌFẸ́ Ìfé jé ohun àrà tí Olórun da tí ó gbódò máa joba láàrin omo ènìyàn nítorí láì sìí ìfé, aiyé kò le rójú. Ìfé ni ó lè se ohun …
ÌFẸ́ Kaa SiwajuORÍ Orí àpéré àtété níran, Àtètè gbeni kù f’òsà, Orí mi gbèmí, Orí mi gbémi dé ibire, Orí mi gbémi dé ibi ayọ̀ mi, Ṣe bí orí ni gbéni taa …
ORÍ Kaa SiwajuAYÉ ṢÒRO Ayé ṣòro, Ayé nira, Ẹnu ti ayé fi sọ wípé nkan gún ní wọ́n á tún fi sọ wípé kò rí bẹẹ mọ́, Ayé ní pe olè kówájà, …
AYÉ ṢÒRO Kaa SiwajuÌTỌ́JÚ Àdán dorí kodò o ń wòse ẹyẹ, ẹjẹ́ka ronún wò káwo báyé ti ń lọ, káwo gbogbo o n tí ó n selẹ̀ nílé lòko. Bàbá r’oko olówó nítorí …
ÌTỌ́JÚ Kaa SiwajuẸNU Ọmọ aráyé ẹ jẹ́ ká ṣọ́ra fẹ́nu Ẹnu ní í lani Ẹnu ní í pani Ẹnu ní jin ni sọ́fìn Ẹnu làá fi ń tún ènìyàn ṣe Ẹnu la …
ẸNU Kaa Siwaju