ÌWÀ
ÌWÀ Tọju ìwà rẹ ọ̀rẹ́ mí, Ọlá a máa tàn nílé ẹni, Ẹwà ási máa lọ lára ènìyàn, Ṣùgbọ́n ìwà ní o ku ní kú nígbà abádé inú saare, Èéfín …
ÌWÀ Kaa SiwajuA dá sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò nípa èdè Yorùbá, àṣà àti ìṣe ilẹ̀ kóòtù ojire. Kíkó àwọn ọmọ wa ni Èdè Yorùbá
ÌWÀ Tọju ìwà rẹ ọ̀rẹ́ mí, Ọlá a máa tàn nílé ẹni, Ẹwà ási máa lọ lára ènìyàn, Ṣùgbọ́n ìwà ní o ku ní kú nígbà abádé inú saare, Èéfín …
ÌWÀ Kaa Siwaju
OÚNJẸ Mo gbà oúnjẹ gbó, oúnjẹ ni alákòóso ara, Oúnjẹ ní ọ̀rẹ́ àwò Iyán l’oúnjẹ, Ọkà Lógún, Àìní rárá lá ń jèko Ké ẹnu má di lè ní ti gúgúrú …
OÚNJẸ Kaa Siwaju
AláyéLúwà Ìwòfà pàdé ọba lọ́nà, Ó gbàdúrà kẹ́lẹ́ kẹ́lẹ́, Pé bóyá orí a ṣé, Òun náà a dépò ọba, Láì mọ̀ wípé, Orí adé ò jẹ́rù ọba o fúyé, Lotito …
AláyéLúwà Kaa Siwaju
ÀÌRÍ’ṢẸ́ ṢE Ẹni tó jí láàárọ̀, To jáde nílé, Tó rí bìkan gbà lọ, Yálà iṣẹ́ ojúmọ́ tàbí toṣù, Tó dìrọ̀lẹ́ tó padà wálé, Tó rọ́wọ́ ti bàpò, Tàbí to …
ÀÌRÍ’ṢẸ́ ṢE Kaa Siwaju
ỌMỌDÉ Ewúré o mọlé olódì, Bẹ́ẹ̀ lọ̀rọ̀ ọmọdé rí, Bí a bá na ewúré, A gbo etí nù pépé, Ó tún padà síbi tí ó ti jìyà, Ọmọdé ò mọlé …
ỌMỌDÉ Kaa Siwaju
ÒFIN FÒ LÓJÚ Òfin fẹ́ oto níyàwó Wọn bí ẹri lérè Ẹri oni ìhòòhò Ẹri tí ń yọ̀ ní nínú ìgbèkùn Ẹri náà ní tun pani Ọrẹ òfin ní ìfẹ́ …
ÒFIN FÒ LÓJÚ Kaa Siwaju
ÌTẸ́LỌ́RÙN Ìtẹ́lọ́rùn ni baba ìwà, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe pàtàkì fọ́mọ adamọ, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe kókó, A gbọdọ̀ ni ìtẹ́lọ́rùn, Kí a le rí ayé gbé, Kí a le gbáyé ìrọ̀rùn, Aìní ni …
ÌTẸ́LỌ́RÙN Kaa Siwaju
AṢỌ WÍWỌ Èèyàn lèyí ni àbí wèrè? Asínwín lèyí ni àbí abugije? Ṣé aṣọ lèyí abi kini? Ha! Ayé tí bàjé, Gbogbo ọmọ adáríhunrun tí sọ àṣà nù, A gbé …
AṢỌ WÍWỌ Kaa Siwaju
IRE Ẹjẹ́ ké gb’ayé ṣe rere, Ọjọ́ a kú làá dère, Ènìyàn ò sunwòn láàyè, Ǹjẹ́ a lè rí ohun gidi sọ nípa rẹ tó bá kú, Àbí àwọn ènìyàn …
IRE Kaa Siwaju
AHUN Iṣu mi ọdún yìí N kò ní fẹ́nìkan jẹ Àgbàdo tí mo gbìn yìí Kò ní kan ẹnìkan l’ẹ́nu Ẹran ọ̀yà tí mo yìnbọn sí Tíi mo ba ri …
AHUN Kaa Siwaju