Skip to content
May 3, 2025
  • Facebook
  • Twitter
  • Instagram
  • YouTube
Èdè Yorùbá Rẹwà

Èdè Yorùbá Rẹwà

A dá sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò nípa èdè Yorùbá, àṣà àti ìṣe ilẹ̀ kóòtù ojire. Kíkó àwọn ọmọ wa ni Èdè Yorùbá

  • Ìtàn
  • Ewì
  • Oríkì
  • Àlọ́
  • È̩kọ́
  • Fọ́nrán
  • Nípa Wa
  • Ẹ kàn sí wa
Main Menu

Ewì

Ewì

ÌFẸ́

January 28, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

ÌFẸ́ Ìfé jé ohun àrà tí Olórun da tí ó gbódò máa joba láàrin omo ènìyàn nítorí láì sìí ìfé, aiyé kò le rójú. Ìfé ni ó lè se ohun …

ÌFẸ́ Kaa Siwaju
Ewì

ORÍ

January 28, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

ORÍ Orí àpéré àtété níran, Àtètè gbeni kù f’òsà, Orí mi gbèmí, Orí mi gbémi dé ibire, Orí mi gbémi dé ibi ayọ̀ mi, Ṣe bí orí ni gbéni taa …

ORÍ Kaa Siwaju
Ewì

AYÉ ṢÒRO

January 28, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

AYÉ ṢÒRO Ayé ṣòro, Ayé nira, Ẹnu ti ayé fi sọ wípé nkan gún ní wọ́n á tún fi sọ wípé kò rí bẹẹ mọ́, Ayé ní pe olè kówájà, …

AYÉ ṢÒRO Kaa Siwaju
Ewì

ÌTỌ́JÚ

January 28, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

ÌTỌ́JÚ Àdán dorí kodò o ń wòse ẹyẹ, ẹjẹ́ka ronún wò káwo báyé ti ń lọ, káwo gbogbo o n tí ó n selẹ̀ nílé lòko. Bàbá r’oko olówó nítorí …

ÌTỌ́JÚ Kaa Siwaju
Ewì

IGI Ọ̀PẸ

January 28, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

IGI Ọ̀PẸ Òjìji fì í Aró’gba aṣọ má balẹ̀ Èmi ọ̀pẹ ní jẹ́ bẹ́ẹ̀ Mo wúlò púpọ̀ fún ọmọ aráyé Àsàdànù kò sí nínú ẹ̀yà ara mi Igi mi wúlò …

IGI Ọ̀PẸ Kaa Siwaju
Ewì

Ewì – Ìyá Ni Wúrà

January 24, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

Ìyá,  kíni ọmọ le ṣé lálá sì ìyá? Ìyá tí ó lóyún fún oṣù mẹsan, Ní ìbẹ̀rẹ̀ oyún ìyá o le jẹ, kólé mú, kò lè sún bẹẹ ni ko …

Ewì – Ìyá Ni Wúrà Kaa Siwaju
Ewì

Ewì – Bàbá Ni Jígí

January 24, 2019January 29, 2019 - by Semiat Olufunke Tiamiyu - Leave a Comment

Bàbá ni jígí Bàbá ṣe pàtàkì lára ọmọ Bàbá ṣe kókó, Láìsí bàbá ìwọ ọmọ òlè dé inú ìyá rẹ Bàbá ní pèsè oúnjẹ fún ìwọ àti ìyá rẹ Láìsí …

Ewì – Bàbá Ni Jígí Kaa Siwaju

Posts navigation

Previous 1 2

Oro Tuntun

  • Àrọ̀nì ò wálé oníkòyí ò simi ogun lílọ
  • ÒÒRÙN Ati ÒṢÙPÁ
  • KÍ LO RÍ L’Ọ́BẸ̀ TÍ Ó FI WAARO ỌWỌ́
  • ORÍKÌ
  • Àṣà Ìgbéyàwó

Eka Oro

  • Ìtàn
  • Ewì
  • Oríkì
  • Àlọ́
  • È̩kọ́
  • Fọ́nrán
  • Nípa Wa
  • Ẹ kàn sí wa

E Tele Wa Lori Facebook

Facebook Pagelike Widget

Twitter

Èdè Yorùbá Rẹwà

A dá ojú ẹ̀ro àyélujára yí sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò nípa èdè Yorùbá, àṣà àti ìṣe ilẹ̀ kóòtù ojire. Kíkó àwọn ọmọ wa ni Èdè Yorùbá. Semiat Olufunke Tiamiyu ni o n ko awon oro wonyii.

Etele Wa Lori

  • Facebook
  • Twitter
  • Instagram
  • YouTube

Eka Oro

  • Ìtàn
  • Ewì
  • Oríkì
  • Àlọ́
  • È̩kọ́
  • Fọ́nrán
  • Nípa Wa
  • Ẹ kàn sí wa

E Tele Wa Lori Facebook

Facebook Pagelike Widget
Copyright © 2025 Èdè Yorùbá Rẹwà.
Powered by WordPress and HitMag.
error

Nje e gbadun ohun ti eka, e tele wa lori:

  • Facebook
    Facebook
    fb-share-icon
  • Twitter
    Follow Me
  • YouTube
    YouTube
  • Instagram