IGI Ọ̀PẸ
IGI Ọ̀PẸ Òjìji fì í Aró’gba aṣọ má balẹ̀ Èmi ọ̀pẹ ní jẹ́ bẹ́ẹ̀ Mo wúlò púpọ̀ fún ọmọ aráyé Àsàdànù kò sí nínú ẹ̀yà ara mi Igi mi wúlò …
IGI Ọ̀PẸ Kaa SiwajuA dá sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò nípa èdè Yorùbá, àṣà àti ìṣe ilẹ̀ kóòtù ojire. Kíkó àwọn ọmọ wa ni Èdè Yorùbá
IGI Ọ̀PẸ Òjìji fì í Aró’gba aṣọ má balẹ̀ Èmi ọ̀pẹ ní jẹ́ bẹ́ẹ̀ Mo wúlò púpọ̀ fún ọmọ aráyé Àsàdànù kò sí nínú ẹ̀yà ara mi Igi mi wúlò …
IGI Ọ̀PẸ Kaa SiwajuApá kejì OTUA MÉJÌ Ó di wí pé Bí ẹnìkán bá ń sọ ọmọ lórúkọ Àwọn ọmọ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta yìí ó lọ síbẹ̀. Bí òkú kú fún ẹnìkan, Wọn á ránńṣẹ́ …
ÒTÚÁ MÉJÌ – Apá Kejì Kaa SiwajuẸsẹ IFÁ Apá Kínní ÒTÚÁ MÉJÌ Wútùwútù yáákí; Wútùwútù yám̀bèlé, Ká súré pátápirá, Ká fẹ̀wù àlàárì fọnkun àmọ́di, Lékèélékèé, ẹyẹ ìmọ̀le, Bó bá ṣí lórí ọ̀pọ̀tọ̀, A bà sórí òrom̀bó, …
ÒTÚÁ MÉJÌ – Apá Kínní Kaa SiwajuÀlọ́ oooo Àlọ̀ ọọọọ Ọkunrin kan wa láyé àtijọ́, Ògbójú-ọdẹ ni, ṣùgbọ́n bi ó ti pa ẹran tó, kò fi dá nkan ṣe. Ọ̀pọ̀ igbà, ki ri ẹran ti ó …
ÌJÀPÁ ÀTI ÒGBÓJÚ ÒDE Kaa SiwajuÀlọ́ oooo Àlọ̀ ọọọọ Àlọ́ yìí dá lórí ìgbín àti Ìjàpá Ní ayé àtijó, ìgbín àti Ìjàpá jọ ń ṣe ọ̀rẹ́. Ọ̀rẹ́ kòríkòsùn ni wọ́n ṣe. Gbogbo ìlú ló sì …
Ìgbín àti Ìjàpá Kaa SiwajuA______ Àgbà kìí wà lọ́jà, k’órí ọmọ tuntun ó wó. B______ Bá mi na ọmọ mi, kò dénu ọlọ́mọ. D______ Dídà ló dà l’ọmọ dé ẹ̀gbẹ́, ẹ̀gbẹ́ kìí ṣe ilé …
A B D Olówe Kaa SiwajuÈyí ni Àlọ́ àpagbè fún gbogbo olólùfẹ́ ojú ìwé yìí, mọ lérò wípé ẹ ò gbádùn ẹ. Àlọ́ oooo Àlọ́ ọọọọ Àlọ́ yìí dá lórí Ìjàpá ati ẹyẹ Àdàbà Gégé …
Àlọ́ Àpagbè – Ìjàpá Ati Ẹyẹ Àdàbà Kaa SiwajuÌyá, kíni ọmọ le ṣé lálá sì ìyá? Ìyá tí ó lóyún fún oṣù mẹsan, Ní ìbẹ̀rẹ̀ oyún ìyá o le jẹ, kólé mú, kò lè sún bẹẹ ni ko …
Ewì – Ìyá Ni Wúrà Kaa SiwajuBàbá ni jígí Bàbá ṣe pàtàkì lára ọmọ Bàbá ṣe kókó, Láìsí bàbá ìwọ ọmọ òlè dé inú ìyá rẹ Bàbá ní pèsè oúnjẹ fún ìwọ àti ìyá rẹ Láìsí …
Ewì – Bàbá Ni Jígí Kaa SiwajuẸ kú dédé àsìkò yìí, ṣe àlàáfíà ni ẹ wà? Fún ìgbádùn àwọn tí ṣẹ̀ṣẹ̀ darapọ̀ mọ ojú ìwé yìí. Ìtàn aladidun fún ìgbádùn yìí,ìtàn tí ó rò mó ọ̀rọ̀ …
Ṣe Boo Tí Mọ Ẹlẹ́wà Sàpọ́n Kaa Siwaju